Yoruba
Quick Links
Past Questions
Aago márùn-ún idájí ni Şeun ti jí jáde nilé lo wO Okò tíóńlo sí idànrè. Ibùdókò Qjóta ni ó lo kí6 tètè rí okò wò. aago méwàá ni okò tó kún. Ki wón tó dễ Sàgámù ni ọkò ti bèrè sí yọnu. Agbára káká ni Nón fì dé ilé-işé atókòşe kan lébàá Ôgbolú. Kí wón tó ri okò şe tán, aago mérin iròlé ti lù. Géré tí wón dể sebú-Òde ni okò bá tún dẹnu kolè. Ojú ojó ti ń po firi, aago méje ti férèé lù kí wón tỏó dé Orè níbi tí awakò ti so pé òun ò lè lo mó. Seun wá gbà pé òun ti şi rin ní ojó náà. ojó tí kò níí gbàgbé láéláé ni ojó náà jé fún un. Ó ronú eni i òun kókó jí rí ní ojó yi, kò rántí; ó féé mọ bí yóò şe yera fún onítòhún.Ó tó wákàtí kan tíó ti ń wá okò niíràn tí kò rí. Lóji ni òjò bèrè síf rò. Òjò òhún kò tilệ I Abé orùlé ni ó sá sí títí di aago mésàn-án àb ki wón tóó rí okò tí ó kó méta nínú won lo. Déédéé aago méjilá àbò òru ni ó tó wo İdànrè ní ojó tí à ń wi yi.
Méwàá
Méje
Márùn-ún
Mérin
ile ti ń şú
ojúmó ti ń mó
ààjin ti ń jin
òòrùn ti ń kan àtàrí
òjò rò
awakò kò mọ okò wà dáadáa
ó gbà pé òun ni ó kó òsi bá òun
ilè şú
okò ti bàjé kí wón tóó dé Şàgámů
ojú ojó po firí kí ó tóó dé ìdầnrè
ó wá okò fún odidi wákàtí kan
D. ó ko opòlopo işòro ní ojú ònà rè sí ídànrè
Okỳ bàjé sí ỳnà Şàgámù
Öjò tíó rò ní Orè
Ojó kan tí ń kò lè gbàgbé
İrin-àjò sí Ogbolú
Take a test

CBT Simulator
Create and set up a CBT environment to practice for any CBT exam.

JAMB CBT Simulator
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.

WAEC CBT Practice 2026 Simulator
Practice WAEC past questions in a real CBT exam environment.

NECO CBT Practice 2026 Simulator
Prepare for 2026 NECO exams using real past questions in CBT mode.