ÈDĖ: AKÀYÉ
Ka àwon àyokà isàlệ wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé òkookan won (1-10)
. Fadékémi jé omo òrukàn tí ó si rewà lóbinrin. Láti kékeré ni ó ti ń wè nínú iyà. Ó ń gbé lódo
Adébáyo,.àbúro babá rè. eni ti o fi iyà pá a lóri doba. títí tí ó fi sá kúro níbè. ilú Aráròmí ni o så lo ni ó ti di aláàárù. Ô tun. dán isé aponmità wó , béè ló tún sisé. omoódó lódo Amòpé Oloúnje. sùgbón Sugbón.kåkà ki ewé àgbon rè rò. lile ló n le sí i.
idi isé bírisopé tí ó tún lọ : se ni Dékúnlé omooba ti pàdé rè, tí ewà rè si wò ó lóju. ó bá a soro, oro won si wo. Dékúnlé wá. bóso iyà lárarè. ó si sọ ó di iyàwó. Báyií ni orúko ro o Fadékémi. Ô di okan ninúủ iyàwó olór ilú, ó si bèrè sí ní yí ninú olá.ninú olá.
Léyin ogún odún tí Abèní ti wolé oko ni ó tó rómo bí. Ó ti relé aláwo, relé onísègùn fún òpòlopò odún. Gbogbo Aàfáà tí ó gbúròó agbára won ni ó ti dàn wò pátá. Kódà, àimoye osù ni ó ti lo lábé ààbò orísirísi wolii. sibè pàbó ni gbogbo rè já sí. ò ti so. irètí nù. pátápátá, Gbogbo ayé ni o ti ró o pin. Àwèní iyá oko rè gbàgbó pé okùnrin ki í yàgàn, Éyí ni ó mú un fé iyàwó miíràn fún omo rè. dún keji tí iyàbó wolé olálérè ni o bị Adétólá, ó si tún bí Gbóláhàn àti Dàmólá ni tàléntàlé.
Nitorí.pé.ile àánú.Olórun ki í sú.léyin ogún. odún ti.Ábèní ti wolé. oko..Olórun. dá a lóhùn. Ole.ayo.so. nínú re. Ibęta ni ó si fi oyún náà bí.
Ta ni ó ń ji yà láti kékeré rè?
Işệ wo ni Fadékémi kókó se?
Ibo ni Dékúnlé ti pàdé Fadékémi?
Akolé tó bả àyokà yií mu jù ni ?