Şàlàyé kóńsónánti ằránmú asesilébù
b. Ko orò tí ó ní kóńsónánti aranmu aşesilebu ninu ki o si fala si idi kóńsónáňti àránmú asesilébù náà (Àkíyèsí: fi àmi ohùn sí ori àpeere )
Kóńsónànti àránmú aşesilébù ni kóńsónàňti àránmúpè tí ó máa ń dúró [gégé bí silébù] nínú orò Yorùbá. ó sì gbódò le [gba àmì ohùn] sórí gégé bí ti fáwéli. Apeere: m, n.
b. Apeere: Gonbó, Oronbó, Gban.gba, Duhdú, Péńpé, Bínńtín, Ipánle, İpéhpéjú, Kòħkò, Gon.go, Bám.gbóşé, Wán,dé, Pan.la, Dáńfó, Géidé, Anjộnú, Ögòngò, Pàńti, Ôjwòran, Renti, Olábím,tán
*Akíyèsí: Apeere wonyí tàbí èyí yòówů tó bá bá lànà yií mu yóo gba máàki sùgbón rántí pé lilo arni ohůn pon dandan. Láisií àmi ohùn tó tònà o ko le gba máàki kankan.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}