Asénupè: końsónànti tí a pè nígbà tí aféfệ èémí di si èyin àwon Àfipè fún igbà díệ, kí ó tó wå tủ sita pèlú ariwo ní onà işenupè yii je mo. Ni lilo ònà işenupè yii, àfàsé gbódò gbé sókè láti di onà káà imú. Åpeerę: b, t, d, k, g, gb, kp.
ii. Afúnnupè: kóńsónànti tí a pè nígbà tí àwọn Afipè bá fi àyè tóóró sílè fún aféfé èémí láti bá jáde pèlú ariwo ni à ń lo ònà isenupè yií fún. Apeere: f, s, ș, h.
iii. Asésí: kóńsónànti tí a pè nígbà tí aféfé èémí dí sí èyin àwon Afipè fún igbà díệ bíi àsénupè, sùgbón tí aféfé èémí náà ń tú jáde díèdíè bíi ti àfúnnupè ní onà isenupè yii ję mó. Āpęere: j/.
iv. Aránmú/Åránmúpè: kóńsónànti tí a pè nígbà tí àfàsé kò gbéra sókè láti dí ònà ihò imú, tí aféfé èémí si ráyè jáde sí ihò imú ní ònà isenupė yií ję mó. Apeere: m, n.
v. Aréhón: kóńsónànti tí a pè nígbà tí a gbé igórí ahón sókè tí a si ká a séyin, tí igórí ahón yií wá lu èrigi nigbà tí ó ń padà bò ni ònà isenupè yii je mó. Apeere: r.
``pätápátá ní àárín enu tí aféfé èémí si ñ gba ègbé enu kan tàbí ègbé enu méjèèji jáde ni à lo onà isenupè yii fún. Apęere: I.
Vii. Àséèsétán: kóńsónànti tí a pè nígbà tí àwon Afipè bá súnmó ara won şùgbón tí wọn fi àyè silè fún aféfé láti gbà jáde pèlú ariwo díę ní onà isenupè yií ję mó. Apęere: y/[j], w.
*Àkíyèsí: BÍ ó bá wù ó, o lè kọ àwon àpeerę re ní ilànà fonetíiki.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}