a. Isèlè búburú kan tí n kò le gbàgbé láéláé
b. Isé lòògùn işe
c. Ojà kan ní agbègbè mi
d. İwé kíkà dára ju isé kikó lo
e. Ko létà sí ègbón re tí ó wà ní ilè òkèèrè láti se alàyé igbáradi tí ò ń şe fún idánwò àşekágbá re, kí o si béèrè irànwó nípa àwon ohun tí o nilò.
İşèlè búburú kan tí n kò le gbàgbé láéláé
-ifäàrà: Èrò rẹ/òrò àkóso nipa ori-orò -Kókó-orò:
i. işèlè tí o kò le gbàgbé láéláé
ii. Ojó tỉ isèlè náà wáyé
iii. Eni/àwọn tí ở sele sí
iv. Ibi tí ó ti sele
v. Ohun tí ó fa såbàbí isèlè naa
vi. Alàyé bí işèle yii se şelė/wäyé
vii. Njé èniyàn kú/dúkiá sòfò nínú işèlè náà?
viii. Ipa tí àwon ará àdúgbò/àwon èniyàn sà láti şe irànlówó/dékun işèlè náà
ix. Ipa tí o kó níbi işèlè náà
x. Àyorísí ipa tí wón sà náà
-İgúnlè: Òrò ikádií tó bá orí-orò mu
B. Işé lòògùn işé
-İfáàrà: Èrò re/òrò àkóso nípa orí-orò
-Kókó-orò:
i. Itumò 'isé lòògùn işé
ii. Eni tí ó bả ń sisé yóò rí je, yóò rí mú , yóò ri ná, yóò rí lò, yóò wúlò fún ìdilé, ebí, ara ati ore yóò lówó lówó láti tún ayé ara rè se
iii. Eni tí ó bả jé ole alápámáşisé yóò máa ráhùn, yóò si ráảgó
iv. Åpęerę/fitàn şókí tí ó fi idí orò yi múlè.
d. lgúnlè: Orò ikádií tó bá orí-orò mu
*Àkíyèsí: Bí asèdánwò bá da ewì 'Isé lòògùn işe lásán ko fún irú àròko yií kò ní gba máàki nitorí kií şe èrò tirè.
D. Ojà kan ní agbègbè mi
-İfáàrà: Erò rẹ/orò àkóso nípa orí-òrò -Kókó-orò:
i.Orúko ojà náà
ii. Orúko àdúgbò tí ó wà mu,
iii. Akókò tí wón ń ná ojà náà: oioojúmó, alaale, oroorún, isiisán, abbl
iv. Ápèjúwe bí a şe kó oja náà
vi. Etò ojà náà
vii. Imótótó ní ojà náà
viii. ÀWon ohun tí a lè rí rà nínú ojà náà
ix. İşàkóso ojà náà (ijoba/ilú)
- lgúnle: Oro ikádii tó bả ori-orò mu.
E. İwé kikà dára ju isé kikó lo
(a) İfáàrà: òrò àkóso nípa orí-orò/èrò rę
(b) Kókó-òro:
Bí iwé kíkà se dára ju işé kikó lọ:
i. Önà iròrùn ni owó ń gbà wolé fún eni tí ó bả ka iwé dé ojú àmi tó sì rí işé gidi se
ii. Ekó máa ń fara hàn nínú ń ní isé tí alákòwé bá ń sé
iii. İwé kíkà máa ń fun èniyàn ní imò tó gbòòrò ju işé kikó lọ.
iv. Alákòwé sáábà máa ń ní ànfààní láti rówó mú ju eni tí ó kósé Jo nínú ètò isèjoba ode-ònií.
v. İwé kíkà máa ń mú kí isé kíkó rorùn.
Bí isé kikó se dára ju iwé kíkà lọ:
i. Eni tí ó bá kósé tètè máa ń rí se ju eni tí ó bá ka iwé lo.
ii. ÀWọn tó kósė tètè máa ń se igbéyàwó tỉ wón si ń bímo, tí won si máa ń ni ibùjókòó.
iii. Akóşé-mosé miíràn ń gba alákòwé sisé bí işé rè bá gbòòrò tán.
iv. Åwon akósé-mosé ki í wá işé kiri, işė àdáni ara won ni wón máa ń se.
(d) lgúnlè:òrò ikádii tó bá ibi tí o fi sí mu.
*ÅKíyèsí: Irú àròko aláriyànjiyàn yií gba kí o gbé apá otún pèlú òsi yèwò kí o tó wá fi ibi tí o faramó gan-an hàn nínú igúnlè rę.
E. Létà sí ègbón re tí ó wà ní ilè òkèèrè láti se àlàyé igbáradì tí ò ń se fún idánwò àşekágbá re, kí o si béèrè irànwó nipa àwon ohun tí o nílò.
Létà sí ègbón rẹ - (Létà gbèfé)
1. Àdirési akolétà àti déèti
ii., İkíni ibèrè: Egbón mi tòótó/owón
iii. Kókó-òrò:
-Akitiyan àwon olůkó: şÍşe idánilékòó fún àwon akékòó léyin àkókò ilé-èkó
-Akitiyan akékòó fúnra rè bíi kíkàwé lóru; lilo sí kilbàsi déédéé; bíbéèrè ibéèrè lówó olùkó; yíyá iwé ní ilé-ikàwé; síse ijíròrò elégbéjegbé; síşe àgbéyèwò àwon ibéèrè tó ti kojá, dídín àkókò eré àti fàáji kù, abbl.
-Bibéèrè àwon ohun tí o niílò bí owó ilé-èkó; iwé i kò ní; aşo ilé-èkó titun; oúnje lórişirişi bi miliki, ti, súgà, abbl.
iv. íkíni iparí
v . Orúko akolétà
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}