Şålàyé sóki lóri òkòðkan àwọn wònyl:
i. Obakan
ii. Opó
iii. Àpón
iv. Àrèmo
v. Beere
i. Obakan: Eyí ni àwon omo tí bàbá kan náà bi sùgbón iyá otootò ni ó bí won. Awon omo tí ó tan nípa bàbá kan náà.
ii Opó: Obinrin tí oko rè ti kú tí kò si ti i fé clòmíràn.
iii Apón: Okùnrin tí ó ti bàlágà tí kò si tí i fé iyåwó.
iv. Arèmo: Éyí ni àkóbi (oba) lókùnrin tàbí eni ti ó dàgbà jù lo nínu awon omo (oba) lókùnrin.
V. Beere: Eyí ni àkobl eni lóbinrin.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}