sàlàyé òkoòkan àwon onà ìşénupè wònyí kí o si fi kónsónánti kookan şe àpeere rè:
a. Afegbé-ęnu-pè;
b. Aréhón;
d. Àsési;
e. ÀSéèsétán;
e. Aránmúpė/Aránmú
a. Afegbé-enu-pè: Iró kóńsónànti tí a pè nígbà tí (aféfé) èémí bá ń gba ègbé enu kan tàbí méjèèji jáde. Ápęere: I
b. Aréhón: èyí ni kóńsónànti tí a gbé jáde nípa kíká ahón kò sókè àti séyin tí abé iwájú ahón yóò sì lu èrigì léekan şoşo (nígbà tí ahón bá ń padà bò sílè nínú enu) iró kóńsónànti tí a pè nígbà tí (aféfé) èémí fé kojá igórí ahón tí a fi ń pé iró yií tó béệ tí àfipè yií fara gbá ibi-işęnupè. Åpęerę: r
d. Àsésí: İró kóńsónànti tí (aféfé) èémí máa ń dì sí èyìn àwon àfipè fún igbà díệ (bí igbà tí a bá fé pe irò àsénupè) şùgbon dípò kí (aféfé) èémí náà tú síta léekan náà, díèdíę ni àwon àfipè máa ń pínyà (kí aféfé tó tú síta). Apęere: j
e. Aséèsétán: iró kóńsónànti tí a pè nígbà tí ipò ahón nínú káà enu dàbí igb à tí a bá fé pe iró fáwéli 'I' tàbí 'u'. iyàtò ni pé idíwó díệ wà fún jijáde èémí tí ó sì jé kí iró tí ó ń dún ní híhó aféfé. Apeerę: y, w.
e. Aránmúpė/Aránmú: ni iró tí a pè nígbà tí àfàsé wá sílè/kò gbéra sókè láti dí ònà ihò imú (Aféfé). Éémí kò sì lè ti enu jáde nítorí pé àwon àfipè ti dí ònà enu. Eyí jé kí (aféfé) èémí jáde (Aféfé). áti ihò imú nikan, tí a ó si ránmúpe àwọn iró náà. Apeęre: m, n.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}