Edè Yorůbá ni kí o fi dáhùn gbogbo ibéèrè ki o si lo àkotó òde òni àti èdè- iperí Yorùbá.
a. Yunifásíti tí mo fé lo.
b. lgbà ipónjú làả mòré.
d. Ijànbá kan tó selè ládùúgbò mi.
e. Anfààní tí ó wà nínú iwé iròyin kíkà.
e. Ko létà sí òré rẹ láti gbà á níyànjú nípa àwon nhkan tí ó gbodò se láti gbáradi fún idánwò àsekágbá tí ó ń bò lónà yií.
1.A. Yunifásiti ti mo fe lo.
a. Ifäàrà: Oro-àkóso tió bả ori-orò mu
b. Köko-òrò:
i. Orúko Yunifäsiti naà
ii. İlú, ipinlè tàbi orilè-èdè ti ó wà
iii. Bóyå ti ijoba ni tàbi tì aladàäni
iv. Awon orişirisi èka èko / imo tỏ wà nibè
v. Eko ti asèdanwò fe lo ko nibè
vi. Idi ti asèdânwò se yan ilé-èko naà láàyo
d. Igúnlè: oro ikädii tó bả orí-orò mu.
B. İgbà iponjú làả mộre.
a. Ifaàrà: òrò-àkoso ti ó bả ori-òrò mu
b. Kökó-òrò:
i. Ohun ti ó lè fa iponjú: b.a. ilé olórogún, ikú obi, àfowofà, àjálů, àisàn, abbl.
ii. Orisirisi iponju ti ó wà: àisàn, àiromobi, àirise, àirokofė, ogun, abbl.
iii. Irufe adúrótini tí a nilò nigbà iponjú: òre gidi, iyàwó/oko, ará/mòlėbi, abbl ti ó lè báni kệdùn, jiyà, abbl.
d. Igúnlè: òrò ikádiỉ tó bả ori-oro mu b.a. èko tàbi ìmoràn tỉ a ri ko nínủ ori-orò yiỉ ni pể kỉ a wo èniyàn dáadaa kí a tó gbára lé e nitori pé owo-epo ni omo aráyé ń bả nì lả.
D. Ijànbå kan tó şelè ládùugbò mi.
a. Ifäàrà: Oro-àkoso tí ó bả ori-oro mu
b. Kökö-orò:
i. Irúfé ljànbå tó selè.
ii. Asikò ti ljànbå näà selè.
iii. Ibi ti ijànbá náà ti şele.
iv. Ibi tí o wà nigbà ti Ijànbå naà selè.
v. Ohun ti ó sokùnfà ljànbả,
vi. Bi ljànbả náà se şelè gan-an.
vii. Akitiyan onirúurú èniyàn/àjo lati panå Ijàħbả àti náà.
vii. Àyorisií ljànbå náà.
viii. Bóyá Ijànbå náà kan aşèdanwó.
d. İgúnlè: orò ikádi tó bả òri-òrò mu.
E. Anfààní tí ó wà ninú iwé iròyìn kikà.
a. Ifáàrà: Orò-àköso tí ó bả ori-òrỳ mu.
b.Kókó-orò:
i.Orisirişi iwé iròyin ti ó wà: ba. olojoojúmo, àtigbàdégbà, elédè Gèesi, elédè Yorùbå, ajemo- n erě-idárayá, ajemo-ètò-orỳ-ajé, åkågbådùn (b.a. àwòrerin-in), abbl ajemo-
ii. Ànfààni: fún mímo ohun ti ó ń lọ ni àyika eni àti ni àgbáyé: fün àfikún imò, ogbộn àti òye b.a. işèlè kảri-ayé, òrò tỏ n lo; fün ipolówó, ipolongo,ikédè; fún wiwá isé; fún síse iwadii, abbl.
d. lgúnlè: orò ikádií tó bả ori-orò mu.
E. Létà si òré rẹ láti gbà á níyànjú nipa àwon nnhkan tí ó gbodò se láti gbáradi fún idánwò àşekágbá tí ó ń bò lónà yií
. * Létà gbèfé ni èyí:
i. Adirési akolétà àti déèti
ii. İkíni ibèrè
iii. idí tí o fi kọ létà yii
iv. Orişiríşi imoràn lórí igbáradì fún idánwò b.a. yíyę nóòti wò, ijíròrò láàrin egbé eni lóri idánwò, fifi àwon iwé idánwò àtijó dánra wò, lilo sí kíláàsi déédé, fífi etí sílè sí olùkó, abbl.
v. İkíni iparí
vi. Orúko akolétà
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}