Dárúko orísi àsikò méii tí ó wà èdè Yorùubá
b. Kọ àpęęrę kòòkan fún atóka àwon wúnren Wónyi :
i
i. ibá işèlè atęrerę
ii,. ibá isèlè bárakú
iii. ibá işèlè àşetán
iv. àsikò ojó iwájú
d. Fi gbólóhùn kan se àpeere wúnrèn kòòkan ti o ko atóka rè ní
Orísi àsikò méji tí ó wà nínú gírámà ède Yorùbá ni:
i. àsikò ojó iwájú
ii. àsikò àfànámònií
b. Ibá-isèlè
Atóka
i. ibá-işèle atererę
ii. ibá-isèlè bárakú a måa, máa ń
ii. ibá-işele àşetán ti, tí n
İv. àsikò ojó iwájú a, yóò, o, máa á.
d. Aterere: ń- Mò ń jeun, ojò ń rò
Bárakú: a maa; maa n - Olú a máa kawe, Ààrá máa ń sán nígbà òjò.
Àşetán: ti, ti n- Bólá ti jęun, A ti ń retí rẹ
Àsikò ojó iwájú: a, yóò, o, , máa - Àwon èro wå, Olá yóò lo,-Màmá ó lo,-Bàbá máa tètè de
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}