Şàlàyé iyàtò tó wà láàrín òrò -àpónlé àti òrờ àpėjúwe .
b. Ko àpęerę gbólóhùn mérinmérin lóri òkoòkan kí o si fàlà sí idí òrò-àpónlé tàbí òrò-àpėjúwe ó wà nínú gbólóhùn koòkan
koğkan 5a. Dárúko orísi àsikò méii tí ó wà èdè Yorùubá b. Kọ àpęęrę kòòkan fún atóka àwon wúne 1. ibá işèlè atęrerę il,. ibá isèlè bárakú li. ibá işèlè àşetán iv. àsikò ojó iwájú nínú giráni o ko atóka rè ní 5(b) İPÍN B: LÍTÍRÉŞO d. Fi gbólóhùn kan se àpeere wúnrèn
*Àkíyèsí: Amì ohùn pon dandan.
a. Orò - àpónlé ni òrò tí ó máa ń pón òro-ise tàbí àpólà-işe nínú iso. Ó máa h fi kún itumò òrò-ise tàbí itumò àpólà-işe ninú gbólóhùn. òrò åpėjúwe jé wúnrèn tí ó ń yàn òrò-orúko. Ó máa ń fé itumò òrò-orúkọ lójú ni.
b.i. Apeere rộ-àpónlé nínú gbólóhùn
Kólá sùn( fonfon)
Àlàbí ń làágun( yòbò)
Omo náà sáré( tete )
Olú rin (dièdiè)
Omo náà pupa (foo)
ii. Åpeerę òrò-àpèjúwe nínú gbólóhùn: Agbò (funfun)ni wón pa
Omo( rere) ni Adé
Ilé (kékeré) ni mo fe
Abíólá féràn èbà (tứtù)
Aso( pupa)kò wù mí
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}