Şàlàyé ní şókí lórí ilànà méji ti à n gbà yá òrò wọnủ èdè Yorùbá
b. Kọ è èdà òkoòkan orò wònyí ní ède Yoribả gégé bi òro-àyálò:
i. blue
ii. driver
iii. hospital
İv. milk
v . doctor
vi. Andrew
vii. Crayon
viii. Belt
ix. Minister
x. chalk
A. ílànà Afetíyá: Éyí ni fífi etí kó bí òro náà ti dún, kí a si yá a bée. Oun ni òrỳ àyálò tí a yá ní ibámu pèlú bí a ti gbó ọ tàbí bí elédè şe pè é.
Åpeere: bible = báíbù, council = káńsù, table = tébù, Peter = Pítà abbl.
ii. İlànà àfojúyá: Èyíni wíwo orò bí won se kọ ó, kí a sì yá a bée. Ôun ni òrò-àyálò tí a yá ní ibámu pèlú bí elédè se ń ko ó sílè.
Åpeęre: bible = bibéli, table = tábìli, Peter = Pétérù abbl.
b.i. búlúù
ii. dírébà/dérébà/díréfà
ii. hosibítù/osibítů/osipítù
iv. mílfiki vi. Ańdérù
v. dókítà/dókítò/dókítà
vi. Ańdérù
vii. Kereyónù
viii. Bélîti
ix. Mínísítà
v. dókítà/dókítò/dókítà
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}