WAEC and NECO CBT App for Mobile Devices - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Post UTME Past Questions Agent

2011 WAEC Yoruba Theory Se àlàyé ijiyà tí ó wà nínú àsà ibílè Yorùbá fún iwà odaràn wònyí i....

Yoruba
WAEC 2011

Se àlàyé ijiyà tí ó wà nínú àsà ibílè Yorùbá fún iwà odaràn wònyí

i. lpaniyàn;

i. Jiji omo gbé;

ii. Agbèrè şişe;

iv. Olè jijà;

v. Éké síse

Post-UTME Past Questions - Original materials are available here - Download PDF for your school of choice + 1 year SMS alerts
Your School's Whatsapp Group - Join Us now
WAEC and NECO CBT App for Mobile Devices - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Explanation

i. İpàniyàn

Eni tí ó bá mòomò pa èniyàn, pipa ni won ả pa á.

Wón lè bệ e lórí kí wọn fì bọ Ôgún.

Wón lè kan orí rè mógi nídií Ogún.

Wón lè so ó kó títí tí yóò fì kú.

Wón lè dáná sun ilé rè, kí wón si lé idilé rè kúrò nilùú.

 ii. Jijí omo gbé

Wón máa ń ta ajómogbé sí oko erú.

Wón lề fi í

si àhámó/inú túúbú/èwòn.

Wón máa ń lé ajómogbé kúrò ní ilú, bi wón bả rí omo tó jí gbé gbà. Pipa ni won yóð pa á bí ở bá ti pa omo náà.

Wón lè fi orò gbé e.

iii. Agbèrè sise

Tita lóji

Wón le tú okùnrin àti obinin náà sí ihòhò/fi wón şe èsín ojútáyé.

Won a ní kí okùnrin tó sàgbèrè san owó itanran fún oko obinrin náà.

Bi obinrin bá tipa àgbèrè lóyún, omo tí ó bá fi oyůn náà bí, oko rệ ni wọn yóò gbé e fún Wón lè ni kí ó lo sisé sin okolóbinrn náà/so ó di iwofà

Wón lẻ lé e kúrò ní ilú bí ó bá jé àlejo

iv. Olè jíià

Wón máa ń nà wón, wón á si fi olè se èsín ojútáyé

Wón lè so ó di iwòfà fún eni tó jà lólè

Wón lè ní kí ó san owó itanràn fún eni tó jà lólè

Wón lè lé e kúrò nílùú.

Wón lè fi í sí àhámó fún igbà díệ.

Wón lè pa á pàápàá jù lọ adigunjalè.

v. Eké sişe

Wón máa ń pa èké

Wón lè fi se èsín ojútáyé

Wón lè fi orò lé e kúrò nílůú.

Wón lè fii bọ òrisà.

Wón lè gba ohun iní rè bí oko àti ilè bí wón bả lé e kúrò níluú.

Report an Error Ask A Question Download App
Post-UTME Past Questions - Original materials are available here - Download PDF for your school of choice + 1 year SMS alerts
WAEC and NECO CBT Software for Computers and Laptops - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Your School's Whatsapp Group - Join Us now

Contributions ({{ comment_count }})

Please wait...

{{ settings.no_comment_msg ? settings.no_comment_msg : 'There are no comments' }}

Quick Questions

Post your Contribution

Please don't post or ask to join a "Group" or "Whatsapp Group" as a comment. It will be deleted. To join or start a group, please click here

{{ quote.posted_by.display_name }}
{{ settings.form_textarea_description }}