a. Ode etilé ní ayé àtijó:
i. Etí ilé ni wón ti máa ń se ode tiwon.
ii. Won ki í ló sí igbé àlosùn.
iii. Won máa ń kun/sun pápá.
iv. Won máa ń rú igbé.
v. Awon ni wón máa ń de pàkúté/èbiti, abbl.
vi. Awon eran tí won máa ń sáábà pa ni: òkété, èkúté, okéré, ikún, òyà, eye lórişirisi, abbl.
vii. Won kì í sáábà ta eran ti won bá pa; jije ni fún won.
viii. Abòsé ni wón máa ń fi isé ode se.
b. Ode aşóde ní ayé àtijó:
i. Awon ode alágbára ni ó máa sáábà sode.
ii. Wón wà fún ààbò ilú.
iii. Ojúse won ni láti rí i pé olè ò já láàárín ilú.
iv. Won ki í gbowó isé won bí tòde oni sùgbón ilú máa ń tójú won.
v. Abosé ni wón mảa ńfi i se.
vi. Oru ni won máa n sisé won.
vii. Wón máa n ní ohun àmúşagbára.
viii. Wón máa ń pín ilú sí àdúgbò- àdúgbò láti şó.
ix. Bi ogun bả dé, àwọn ló máa kỏ ara won jo láti lọ jà fún ilú wọn.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}