Eré Àrín
i. Arín títa jé òkan nínú àwon eré idárayá tí a máa ń se nígbà tí owó bá dílè ní iròlé.
ii. ÉSo itàkùn kan ni àrín, ara rè ń dán, ó sì tóbi ju omo ayò lọ.
iii. Awon omodé àti àwon géńdé ló ń ta àrín.
iv. Orí ilè tí ó tú tỉ ó si fè ní gbangba ita ni a ti ń ta àrín.
v. A ó fa ilà onígun mérin; ká lè mọ ojú agbo àrín. A ófi ilà pín agbo yií sí ilé méjl.
vi. Eniyàn méji sí méfà tàbí jù bée lọ lè ta àrín; wonó pín ara won sí onà méji.
vii. A ó pín àwon àrín bí méwàá (10) tàbi jù bée lo tí ati kó kalė sí méji. A ó jé kí àrín nåà séku biíi mérin sílè.
viii. A ó fi àwọn àrín tí a pín lélè káta-kåta sí ojúlé kòòkan. Arín tó sékù ni won ỏ fi bèrè àrin títa.
ix. Eyin agbo àrín ni àwọn òsèré yóò ti máa ta àrín won sí agbo àrin tí àwon alätako won.
X. BÍ àrín tí wón ta bá ti fara gbún òkan nínú àrín ti alátakò tàbí ti ó șí okan ninu àrín ti àwon alátakò nípò, a je pé wón 'pa' á niyen.
xi. BÍ wón bá ta àrín ní àwon alátakò yóó máa sa gbogbo èyí ti wón pa/ti ó lulè/ti a sí nípò kún ti owó won.
xii. Bí apá kín-ín-ní bá ti ta tán ni yóò kan apá keji títí tí won ó fì 'pa' gbogbo àrín ti apá kan tán.
xiii. Awon tí àrin won bá koko tán ni agbo won ni opè. Awon tí àrín won sekù ni agbo won ni ota.
xiv. Awon èrò iwòran nídii àrín máa ń fi s àwọn opè sèfe.
xv. Awàdà/ifini-sefe agbo eré àrín kì í fa ijà. Erín ni wón fì ń rín.
xvi. Lára ànfààní àrin títa ni:mímú inú éni dùn, irépò láàárín àwon òntàrín; èkó ifojúsůn; èkó isirò, abbl.
xvii. Lára àléébủ àrín títa ni: mímú kí òntàrín má rí àyè bikítà fún ebi/isé ilé; ifinisèfè idí àrín lè bó sí åpò ibínú elomíràn, abbl.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}