Se àpėjúwe àwon òrò-arópò-orúko afarajórúko tí ó wà nínú òkòòkan àwon gbólóhùn wonyí:
a. Emi ti gba á.
b. Àwá ti gbó.
d. Won kií gbóràn bòrò.
e. Oun gan-an ni mo fún un.
ę. Eyin wo ni è ń pariwo yen?
f. Åwa ni oríire kàn.
i. Emi - òrò-arópò-orúko afarajórúko eni kíní, eyo, olůwà
ii. á - orò-arópò-orúko eni keta, eyo, àbò (orỳ- işe)
b. Awá - orò-arópò afarajórúkọ eni kíní, opò, olùwà
d. Won - òrò-arópò-orúko eni kęta, po, olùwà
e. i. Oun - orò-arópò afarajórúkọ eni kęta, eyo, abò (oro-atókùn)
ii. mo - òrò-arópò-orúko eni kíní, eyo, olùwà
iii. un - òrò-arópò-orúko eni kęta, àbò (orò-işe)
ę. i. Éyin - oro-arópò afarajórúko eni keji, opo, olůwà
ii. - òrò-arópò-orúko eni keji, opo, olùwà
f. Àwa - orỳ-arópò afarajórúko eni kíní, ópó , àbò (orò-işe)
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}