Your School's Whatsapp Group - Join Us now
WAEC and NECO CBT Software for Computers and Laptops - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now

ÈDĖ: AKÀYÉ Ka àwon àyokà isàlệ wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó...

Yoruba
WAEC 2015

ÈDĖ: AKÀYÉ

Ka àwon àyokà isàlệ wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé òkookan won (1-10)

. Fadékémi jé omo òrukàn tí ó si rewà lóbinrin. Láti kékeré ni ó ti ń wè nínú iyà. Ó ń gbé lódo

Adébáyo,.àbúro babá rè. eni ti o fi iyà pá a lóri doba. títí tí ó fi sá kúro níbè. ilú Aráròmí ni o så lo ni ó ti di aláàárù.  Ô tun. dán isé aponmità wó , béè ló tún sisé. omoódó lódo Amòpé Oloúnje. sùgbón Sugbón.kåkà ki ewé àgbon rè rò. lile ló n le sí i.

idi isé bírisopé tí ó tún lọ : se ni Dékúnlé omooba ti pàdé rè, tí ewà rè si wò ó lóju. ó bá a soro, oro won si wo. Dékúnlé wá. bóso iyà lárarè. ó si sọ ó di  iyàwó. Báyií ni orúko ro o Fadékémi. Ô di okan ninúủ iyàwó olór ilú, ó si bèrè sí ní yí ninú olá.ninú olá. 

Léyin ogún odún tí Abèní ti wolé oko ni ó tó rómo bí. Ó ti relé aláwo, relé onísègùn fún òpòlopò odún. Gbogbo Aàfáà tí ó gbúròó agbára won ni ó ti dàn wò pátá. Kódà, àimoye osù ni ó ti lo lábé ààbò orísirísi wolii. sibè pàbó ni gbogbo rè já sí. ò  ti so. irètí nù. pátápátá, Gbogbo ayé ni o ti ró o pin. Àwèní iyá oko rè gbàgbó pé okùnrin ki í yàgàn, Éyí ni ó mú un fé iyàwó miíràn fún omo rè. dún keji tí iyàbó wolé olálérè ni o bị Adétólá, ó si tún bí Gbóláhàn àti Dàmólá ni tàléntàlé. 

 Nitorí.pé.ile àánú.Olórun ki í sú.léyin ogún. odún ti.Ábèní ti  wolé. oko..Olórun. dá a lóhùn. Ole.ayo.so. nínú re. Ibęta ni ó si fi oyún náà bí.

Ta ni ó ń ji yà láti kékeré rè? 

  • A. Dékúnlé
  • B. Fadékémi
  • C. Ảmòpé
  • D. Adébáyo
Post UTME Past Questions Agent
Post-UTME Past Questions - Original materials are available here - Download PDF for your school of choice + 1 year SMS alerts
WAEC and NECO CBT App for Mobile Devices - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Correct Answer: Option B
Explanation
No official explanation is available for this question at this time. Please check contributions posted by others below. If you can provide an explanation to help other student learn, please click here

Report an Error Ask A Question Download App
Post UTME Past Questions Agent
WAEC and NECO CBT Software for Computers and Laptops - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Your School's Whatsapp Group - Join Us now

Contributions ({{ comment_count }})

Please wait...

{{ settings.no_comment_msg ? settings.no_comment_msg : 'There are no comments' }}

Quick Questions

Post your Contribution

Please don't post or ask to join a "Group" or "Whatsapp Group" as a comment. It will be deleted. To join or start a group, please click here

{{ quote.posted_by.display_name }}
{{ settings.form_textarea_description }}