Agbè pàtàki ni Oyèjidé ní agbègbè ibóse. Ki i gbin kòkó, béè ni ki í gbin ògède. Ohun ti ó fi ta àwon egbé rè yọ ni oko àlò tí ó ń dá. A máa tó egbàá mérin. O máa ń gbin ewùrà die, sùgbón èsúrú rè kì í pò púpò. Yàtò sí pé ó jé àgbè, ó tùn gbówó. Lára àwon tí ó bá a pààlà ni Àdisá, Dérin, Arèmú àti Sùúrù. Ogbìn àgbàdo ni ti Àdisá; Dérin a máa dáko rodo; Arèmú àti Sùúrù sì gbádùn gbágùúdá àti ilá ní tiwon. Olè a mảa jà púpò ní agbègbè yií. Púpo nínú àwon àgbè ibóse ti dode àwon olè náà titi sùgbón pàbó ló já si. Ojó tỉ owó pálábả olè kan máa ségi, oko Oyèjidéni ó lo. Léyin tí ó ti palè oko mó láàjin, ó gbé erù; ó fé máa lo. Bí ó ti gbé erù karí ni ó bèrè sí pòòyi lójú kan náà, bệè ni erù kò seẻ sò. Ibè ni ilè mó bả olórò tí àwon olóko dé bá a; wón sì mu un lo sí ilé baálè.
ni Oyèjidé máa ń gbìn.
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}