Ka àwon àyokà isàle wộnyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé okookan wọn.
Omo meta ni Bájo bi. Adàrán ni àkóbí, Dáúdà ó tèlé e;ni Adépégà si ni àbikéyin won. Ojó pé tí Adépégà ti bá Adàrán lo sí Owódé lébàá Itamògån nibi tí Adàrán ti ń şişé. Egbón rè fi i senu ekósé. Léyin tíó kósé si tí ó si yege, o KOja si Orímedù nítòsí Lekí..
O rówó mú níbè. Ibè ni Fádípe tí ó si ti ri Fádéke omo Fádipe ti o wá fi saya. Olórun fi opò omo won: Jedá, Fémi, Elisá, Bósè, Koyà àti Kolá. Bi ibe şe gbè é tó, kò gbàgbé ilé. Ở pinnu lati padà sí Isòmù, ilú abínibí rè; gbogbo àwon omo re si tèlé e.
Omo mélòó ni Fádékę bi?
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}