Ohun gbogbo ló ní àsikò tirè. Nígbà tí àsikò tó fún àwon egbeegbé wònyí láti jó kỉ oba ni a sesè tó wå ríran wò. Sé ní ti egbé, wón pò lo súà bỉ olá Olórun: idándè, Omoladé, Ominira, Omóyèlú, Bóbakeye, Ajagungbadé, Obatėkóbò, Qbanibàşírí, Bóbagùnté àti béệ bée lọ. TỈ a bá ní kí a máa to àwon orúko egbé wònyí bí wón şe pò tó, yóð gba odindin ojú-iwé méji níbi tí wón pò dé. Bí oníkálůkù won ti ń jáde lo síwájú Kábíyèsí pèlú èbùn wọn lówó ni àwon òsèré wọn ń lù tèlé won léyìn. Músílíù omo Hárúnà İsòlá ko kísà lórin. Eléré ibílè kan tí won ń pè ní İdàgèrè náà kọ sége lórin. Orí esin funfun ni Jenera Ayinlá wà tó ń korin fún Egbé idándè.
Jenera Àyinlá ni ó
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}