ÈDÈ: AKÀYÉ
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé okookan won.
BÍ ó tilè jé pé Asàké ni ààyò Délé, Olórun kò tètè yònda omo fún un. İyáálé rè, Ảjoké ti bí isun, iyàwó tí Délé e, Anikè, náà ti bí iwàlė. Awon méjèèji a si máa wo Asàké bí olowó-sibí tó kàn wá bá oko won jeun lasan. Gbogbo igbà ni Délé máa ń gbàdúrà kí Olórun tètè dá Aşàké lóhùn. Iparí osù tí isé pàjáwiri gbé Délé lo sí òkè-òkun ni Àsàké déédéé rí i pé òun ti féra kù! Wéré ló te oko rè láago láti fún un ní ì Kàyéfi ni ó jé fún àwon orogún rè láti rí i ní ipò tó wà, wón si ń fojú ilara wò ó. Osù méfà ni Délé lò léyin odi kí ó tó padà wá sílé. Osù keji tó dé ni Áşàké bímo, omọ náà sì jo Délé bí imumu. Ó so ỏ ní Omoniyi. Aşàké so ó ní Olúwajůwá.
Kí ni ó gbé Délé lo sí òkè-òkun?
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}