WAEC and NECO CBT App for Mobile Devices - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Your School's Whatsapp Group - Join Us now

2011 WAEC Yoruba Theory Aàfin oba ilú kan tí mo mò b. ijànbá kan tí ó selè lójú mi...

Yoruba
WAEC 2011

Aàfin oba ilú kan tí mo mò

b. ijànbá kan tí ó selè lójú mi

d. Omi wúlò ju iná mònàmóná lo

e. Okùnfà ikú odó

e. Ko létà sí òró re tí ó wà ní ipinlè miíràn, sàlàyé fún un nípa ètò işèjoba ipínlè re.

WAEC and NECO CBT Software for Computers and Laptops - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Your School's Whatsapp Group - Join Us now
Post-UTME Past Questions - Original materials are available here - Download PDF for your school of choice + 1 year SMS alerts
Explanation

 Aàfin oba ilú kan tí mo mo

İfáàrà - Erò rẹ lórí ori-òrò

Kökó òrò: orúko ilú náà àti gba ibè

-lbi tí ààfin náà wà

-Apèjůwe bí a şe lè débè

-Bi ààfin náà se ri àti ètò ibè

-Ti àtijó ni àbí ti igbàlódé

-Ohun pàtàkì tí a lè rí ní ààfin náà bí àpeere: ònà àbáwolé, káà igbéjó, ibùgbé oba, ibùgbé ayaba, gbòngàn işèňbáyé, ojúbọ òrişà, àgbàlá oba àti béè bée lọ.

-Onírúurú àwọn tí ó wà láàfin, bí àpęerę: ijòyè, ilàrí, omo-esè oba, akowé ba, olópàá oba, akígbe oba, àwon omo-oba àti bee bée lo.

İgúnlè: Ero re/òrò ikádií tí ó bá ori-òrò mu: bí àpeere imoràn fún àtúnse àti béè béè lo.

B. İjànbá kan tí ó şelè lójú mi

i. İfáàrà - Erò re lórí orí-òro

ii. Kókó òrò: Irú ijànbá tí ó selè bí àpęere: ijànbá mótò, oko ojú-irin, okò ofurufú, ijànbă iná, ijànbả omi, ilé tí ó wó àti bée bée lọ

-Ojó, àsikò àti odún tíó selè -Ibi tí ó ti sele

-Kí ni ó fa ijànbá náà

-iròyin isèlè náà ní kikún

-Njé olùrànlówó wà tàbí kò sí. bí àpeere: irànlówó láti òdò ijoba, olópàá, panäpaná, eso ojú pópó tàbí àwon èniyàn (àwon agborodün)

-Ipò tí o wà ninú jànbá náà

iii, lgúnlè: Ero re/orò ikádii ti ó bả or-orò mu B.a. ogbón tí o í kó, imòràn tí o è mú wá nipasè isèlè náà.

D. Omi wúlò ju iná monàmóná lo

İfáàrà: Erò rẹ lórí orí-oro Kókó orò: orísirisi omi àti iwúlò won: omi mímu, omi odò, omi kànga, omi okun,, omi ojò abbl.

Ànfààní omi : À ń mu omi, à ń fi omi wè, à ń fi omi şe iwòsàn yálà ní ònà igbàlódé tàbí ibilè, à ń fi omi se imotótó, a máa ń rin irin-åjò lójú/lórí omi, a fi ń se oúnje, ó wà fún işé oko, ohun Òsin, işé eja pípa, à ń fi pa iná, fifi se iná èléntíriki.

Aléébù omi : A lè kó àrùn láti inú omi bí imótótó tó péye kò bá sí

-irin-àjò lórí omi máa ń léwu nígbà miíràn

-Åpòjù omi lè ba oríşiríşi nnkan jé: ilú, oko, ohun-ini, abbl.

 Anfààní iná mònàmóná: Ó ń fún ni ní ìmólè

-Gbogbo ilé-isé joba tàbí aládàáni ni ó nílò iná monàmóná fún isé won

-Oun ni a fi ń lo àwon èro igbàlódé nínú ilé bí àpeere: rédíò, telifisàn, fáànů, firiji abbl

-BÍ kò bá sí iná yóò sòro láti fi èro fa omi

Aléébù iná mộnàmóná : Ó lè pa èniyàn

-Ó lè jó ilé, ilé-isé, ojà, oko abbl.

-Igunle: Orò ikádií lórí ibi tí o fi si

-Akíyèsí: Asèdánwò tó bá ró ilé apá kan, ilàji máàki ni won yóo gbé èrò rè lé, 

E. Òkùnfà ikú òdó

İfäàrà: Alàyé lórí orí-òrò

Kókó-òrò: ẢWon ohun tí ó ń se òkùnfà ikú odó: Ayé ijekúję iwà àgbèrè/panságà/ siná, òkánjúwà/wíwá owó òjji, iwàkúwà okò (sísá eré àsájů), egbé búrukú (kikó egbé òkùnkùn, kikó orékórèé), irinde òru/olè jijà, lilo àti gbigbé oògùn olóró, sişe àfojúdi sí àgbà, àòkàn, akébàjé, jàgidí-jàgan, èsin/òsèlú, aisí itójú tó péye, àşilò-òògùn, àirísé se, ijà orogún, ijäkulė, aigbón, ijàgboro, ifètódunni, ijànbá, oyún sise, imuti-para, agidi.

Igúnle: Imoràn re láti dékun ikú odo.

E. Létà sí oró rę tí ó wà ní ipínlè miíràn, şàlàyé fún un nípa ètò isėjoba ipínle re.

Létà gbèfé ni èyí:

Adirési akolétà àti déèti İkini ibèrè Kókó òrò

- Etò ijoba ti ipínlè re

-Ètò èkó, ètò ilera, ètò igbòkè-gbodo ok, ètò iròyin, ètò orò-ajé, pípèsè işé fún àwon aráalú, pipèsè ohun amáyéderùn, sişe ètò ààbò, ffún àwon obinrin láhfåàní láti kópa nínú ètò isèlú, itójú omodé, òdó, arúgbó, àwon tí èyà-ara pè nijà, sogbédigboro, síşe onà, ètò imótótó

-Awon ohun tí o ye kí ijoba se tí kò se

-İkíni iparí

-Orúko akolétà

Report an Error Ask A Question Download App
WAEC and NECO CBT App for Mobile Devices - Candidates, Schools, Centres, Resellers - 100% Offline -Download Now
Post UTME Past Questions Agent
Your School's Whatsapp Group - Join Us now

Contributions ({{ comment_count }})

Please wait...

{{ settings.no_comment_msg ? settings.no_comment_msg : 'There are no comments' }}

Quick Questions

Post your Contribution

Please don't post or ask to join a "Group" or "Whatsapp Group" as a comment. It will be deleted. To join or start a group, please click here

{{ quote.posted_by.display_name }}
{{ settings.form_textarea_description }}