"Orí òkéré koko láwo, báa wí fómo eni a gbo", èyí ni gbólóhùn tí ó jáde lénu Àkàndé tí í şe bàbá Àlàó, bí omo rè ti ń japoro ikú lóri ibùsùn ní ilé-iwòsàn Márapé ní ilú Dòho. Alàó jé omọ ilú Ôkè-Egàn. Láti kékeré ni İyápé, iyá Alàó ti bà á jé, nítorí pé ó jé ògúnná kan soso ti ó ní. Gbogbo akitiyan Akàndé ní tító Alàó sónà ló já sí pàbó. Àlàó ń jayé alákátá, ó gbé iwà isekúse wò bí èwù. Bí dúdú ti ń wá, ni pupa ń wá sóodè rè, kódà ó férę lè máa gbé wèrè ni àgbésùn. Ayèwò tí ó lọ şe ni ó fi hàn pé Alàó gbà pé iků yá ju èsín, èyí ni ó mú un gbé májèlé je, èyí ti ó so ó di èrò ilé-iwòsàn.
Ki ni ó fa ijaporó ikú?
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}