Mótò méfà ni Awódélé ní: Pijó kan, Mésidísi méj, Isúsů kan, Toyótà kan àti Jipů kan. Mésidisi ni ó máa ń gbé lo síbi isé. Tó bá fé rin irinàjò pàtàki, Jipů ló máa ń gbé lo. Kåsálí awakò rè ń wa kísà. Omo mérin ni Awódélé bí: Kládé làkóbí, Ådůké làtèlé, Kólájo lomo keta ń jé, Yéwándé làbikéyin won lénjélénje. Wón jé okùnrin méji àti obinrin méji. Gbogbo rè se wékú bí idodo èfon. Gbogbo omo tí Omóyeni bí fún Awódélé ló yàn tó yanjú. Awon àgbà ní "Ojú tó ríbi tí kò fó, ire ló ń dúró dè". Kò sí eni tí ó lè rí Awódélé lónií kó gbàgbó wí pé alágbe ni bàbá re. Odún keta gééré tí bàbá re kú ni nhkan bèrè sí ní senu re fún un. ó si ti wà nínú yòtòmi yii fún odún méwàá gbáko.
Ta ni ó kéré jù lójó ori?
Contributions ({{ comment_count }})
Please wait...
Modal title
Report
Block User
{{ feedback_modal_data.title }}